Adédùnkẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Adédùnkẹ́

It is sweet to care for the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-dùn-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
dùn - sweet
kẹ́ - cherish, care for, pet, pamper


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dédùnkẹ́