Adébímitán

Sísọ síta



Ìtumọọ Adébímitán

The crown gave birth to me complete/whole.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Ọlábímtán



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-bí-mi-tán



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
- give birth to
mi - me
tán - complete(ly), finish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adébíntán

Bímitán