Adéṣògo
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéṣògo
1. The crown created glory. 2. One who arrived and made glory.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-ṣe-ògo, a-dé-ṣe-ògo
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyṣe - make
ògo - glory
a - someone who
dé - come, arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA