Adéòtítọ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéòtítọ́

The true crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-òtítọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
òtítọ́ - truth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Adéòótọ́