Abísádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Abísádé

Born into royalty.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-bí-sí-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who (is)
bí - give birth to
sí - into
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Abíádé

Abísádé

Bísádé