Abímisíreolúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Abímisíreolúwa
I have been born into the goodness of God.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-bí-mi-sí-ire-olúwa
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - webí - give birth to
mi - me
sí - into
ire - goodness
olúwa - lord, God
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL