Abímisọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Abímisọ́lá

We birthed me into wealth/success.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Abímbọ́lá



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-bí-mi-sí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - we
bí - birthed, give birth to
mi - me
sí - into
ọlá - wealth, success


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO



Irúurú

Bímisọ́lá