Abímbọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Abímbọ́lá

I was born with wealth/success/nobility/prestige.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-bí-mi-bí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - we
bí...bí - give birth to with
mi - me
ọlá - wealth/nobility/success


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Wándé Abímbọ́lá

  • Bímbọ́ Akíntọ́lá (actress)



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú

Bímbọ́