Abíléolúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Abíléolúwa
1. One born into God's house 2. One born into God's hands
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-bí-sí-ilé-olúwa, a-bí-lé-olúwa-ní-ọwọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one who; webí - to give birth to
sí - into
ilé - house, home
olúwa - lord, God
lé - be added to
ní - have, own; into
ọwọ́ - (a helping) hand
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL