Abíálà
Sísọ síta
Ìtumọọ Abíálà
One born to purity.
Àwọn àlàyé mìíràn
The àlà white cloth is a symbol of the creation god Ọbàtálá, so the name is traced to the devotees of this deity.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-bí-(sí)-àlà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - someonebí - give birth to
(sí) - into
àlà - white cloth (symbol of Ọbatala)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OYO