Abọ́láwarìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Abọ́láwarìn
One who walks in with our wealth/success.
Àwọn àlàyé mìíràn
Compare: Abólúwarìn, Abọ́lárìn
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-bá-ọlá-wa-rìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - someonebá - together with
ọlá - wealth, success, nobility
rìn - walk
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA