Abọ́lárìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Abọ́lárìn

One who walks with nobility.



Àwọn àlàyé mìíràn

It is the short form of Abọ́lárìnwá.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-bá-ọlá-rìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
bá - together with
ọlá - wealth
rìn - walk
wá - come, arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Abọ́lárìnwá