Abọ́dúndé

Sísọ síta



Ìtumọọ Abọ́dúndé

One born during a festival.



Àwọn àlàyé mìíràn

Children born during the native festive seasons, including modern ones like Christmas, Easter, Eid-el-Fitr, etc are given this name.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-bá-ọdún-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
bá - join with
ọdún - festival, year
dé - arrive, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Bọ́dúndé