Abẹ́lẹ́shindọ́gba

Sísọ síta



Ìtumọọ Abẹ́lẹ́shindọ́gba

One who is as prominent as the horseman.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-bá-ẹlẹ́ṣin-dọ́gba



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
bá - together with
ẹlẹ́ṣin - horseman
dọ́gba - be equal to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Abẹ́lẹ́ṣindọ́gba