Abíájé

Sísọ síta



Ìtumọọ Abíájé

One born into industry.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-bí-sí-ajé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - someone
- to give birth to
- into
ajé - business, trade, enterprise


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Abísájé