Aṣaájú

Sísọ síta



Ìtumọọ Aṣaájú

The leader.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Aṣájú



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-ṣe-iwájú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
ṣe - make
iwájú - forward, leadership


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Asiwájú