Àyánlẹ́yẹ
Sísọ síta
Ìtumọọ Àyánlẹ́yẹ
The spirit of the drummer has honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
àyàn-ní-ẹ̀yẹ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
àyàn - drummer; Àyàngalú, the deity/spirit of drummingní - have, own; into
ẹ̀yẹ - honour, celebration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL