Àwòfẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Àwòfẹ́
Loved at first-sight! Beloved! Look and love!
Àwọn àlàyé mìíràn
A cognomen, oríkì.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
à-wò-fẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
à - one who (is)wò - look at
fẹ́ - love, want
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA