Ànúolúwayíkànmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ànúolúwayíkànmí

God's mercy rotated to me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

àánú-olúwa-yí-kàn-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

àánú - mercy
olúwa - lord, God
yí - turn
kàn - to, reach
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Àánúolúwayíkànmí