Ànúolúwapọ̀lórími
Sísọ síta
Ìtumọọ Ànúolúwapọ̀lórími
The mercy of God is plenty on me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
àánú-olúwa-pọ̀-ní-orí-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
àánú - mercyolúwa - Lord, God
pọ̀ - a lot, plenty
ní - on
orí - head, body
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL