Ànjọláọlọ́run

Sísọ síta



Ìtumọọ Ànjọláọlọ́run

We're enjoying the wealth of God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-ń-jẹ-ọlá-ọlọ́run



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - we
- are
jẹ - eat, enjoy
ọlá - wealth
ọlọ́run - God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ańjọlá

Jọlá