Àńyinolúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Àńyinolúwa
We are praising God.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Ayinolúwa.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
à-ń-yin-olúwa
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
à - weń - continue to
yìn - praise
olúwa - lord, God
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL