Àkànṣeore

Sísọ síta



Ìtumọọ Àkànṣeore

Goodness/Favour deliberately wrought.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

à-kàn-ṣe-oore



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

à - someone, an act
kàn - deliberate
ṣe - make, create (something good), do
oore - goodness, gift, benevolence, favour


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
IBADAN