Àjàlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Àjàlá
One who has fought and survived.
Àwọn àlàyé mìíràn
A cognomen, oríkì.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
à-jà-lá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
à - someonejà - fight, struggle
lá - survive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Ọlábísí Àjàlá
Nigerian writer
journalist
and traveller: https://en.wikipedia.org/wiki/Olabisi_Ajala