Àgbáyẹwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Àgbáyẹwá

We're worthy of adulthood/old age.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

àgbà-yẹ-àwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

àgbà - elder
yẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
àwa - us


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL