Àdúràyẹmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Àdúràyẹmí

Prayer favours me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

àdúrà-yẹ-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

àdúrà - prayers
yẹ - befit, benefit, favour
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Yẹmí