Àdùnní

Sísọ síta



Ìtumọọ Àdùnní

The one pleasant to have. Sweet personality.



Àwọn àlàyé mìíràn

A cognomen, oríkì.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

à-dùn-ní



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- one who
dùn - sweet
ní - have


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Àdùnní Olórìṣà (Susanne Wenger). Austrian-Nigerian artist (1915-2009)



Irúurú

Àdùní