Àbẹ̀joyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Àbẹ̀joyè

One who was begged to take a title.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

à-bẹ̀-joyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

à - one who; that which
bẹ̀ - to beg
joyè - to receive a chieftaincy title


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA