Àbẹ̀fẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Àbẹ̀fẹ́

One begged to love, one whom you begged before she loves/marry you.



Àwọn àlàyé mìíràn

Similar to Àbẹ̀kẹ́. Typical Yoruba name without religious input. Usually female name.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

à-bẹ̀-fẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- one
bẹ̀ - beg
fẹ́ - marry


Irúurú

àbẹ̀kẹ́