Àánúolúwakìítán
Sísọ síta
Ìtumọọ Àánúolúwakìítán
God’s mercies never ends.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
àánú-olúwa-kìí-tán
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
àánú - mercyolúwa - lord, God
kìí - does not
tán - finish
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA