Ọyagòkè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọyagòkè

The goddess Ọya (or her devotee) ascends (into greatness).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọya-gùn-òkè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọya - the goddess Ọya
gùn - mount, climb, ascend
ọ̀kè - hill, a higher place, mountain


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL