Ọyámakin
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọyámakin
Ọya knows bravery.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọya-mọ-akin
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọya - Ọya; Yorùbá deity of storms, winds, and the Niger Rivermọ - know
akin - valor, bravery, the brave one
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OYO