Ọwápéjú
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọwápéjú
The (children of the) Ọwá have gathered.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọwá-pé-ojú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọwá - king (especially Èkìtì, Ìjẹ̀ṣà, Oǹdó, and Ọ̀wọ̀ kings)pé - complete
ojú - face
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA