Ọwáníre

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọwáníre

The Ọwá (king) has goodness.



Àwọn àlàyé mìíràn

Ọwá or Ọgwá in this name refers to the Ọlọ́wọ̀, the king of Ọ̀wọ̀.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọwá-ní-ire



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọwá - king (especially Èkìtì, Ìjẹ̀ṣà, Oǹdó, and Ọ̀wọ̀ kings)
- have
ire - goodness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OWO



Irúurú

Ọgwáníre