Ọwánádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọwánádé

The Ọwá (king) has a throne.



Àwọn àlàyé mìíràn

Ọwá or Ọgwá refers to the Ọlọ́wọ̀, the king of Ọ̀wọ̀.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọwá-ní-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọwá - king (especially Èkìtì, Ìjẹ̀ṣà, Oǹdó, and Ọ̀wọ̀ kings)
- have
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OWO