Ọwádímibọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọwádímibọ́lá

The king (Ọwá) has allowed me to meet honor.



Àwọn àlàyé mìíràn

In this name, Ọwá or Ọgwá likely refers to the Ọlọ́wọ̀ of Ọ̀wọ̀, the king of Ọ̀wọ̀ praised as Ọgwá Olúwayé (King, the lord of the world).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọwá-dí-mi-bá-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọwá - king (especially Èkìtì, Ìjẹ̀ṣà, Oǹdó, and Ọ̀wọ̀ kings)
- to allow (jí, jẹ́)
mi - me
- together with
ọlá - wealth/nobility/success


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OWO



Irúurú

Ọgwádímibọ́lá