Ọrẹ̀tọ́pẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọrẹ̀tọ́pẹ́
The deity Ọrẹ̀ is worthy of praise.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọrẹ̀-tó-ọpẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọrẹ̀ - Ọrẹ̀; a warrior and fertility deity associated with farming and weathertó - suffice for
ọpẹ́ - praise, thanks
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE
IJEBU