Ọrẹ̀pìtàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọrẹ̀pìtàn

Ọrẹ̀ (used this child) to add a story/history.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọrẹ̀-pìtàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọrẹ̀ - Ọrẹ̀; a hunting and fertility deity associated with farming and weather
pìtàn - to tell a story; to tell oral history


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Pìtàn