Ọrẹ̀làjà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọrẹ̀làjà
Ọrẹ̀ has stopped the fight.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọrẹ̀-là-ìjà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọrẹ̀ - Ọrẹ̀; a hunting and fertility deity associated with farming and weatherlà - separate
ìjà - fight
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU