Ọrẹ̀bàjò

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọrẹ̀bàjò

Ọrẹ̀ has returned from a journey.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọrẹ̀-bọ̀-àjò



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọrẹ̀ - Ọrẹ̀; a hunting and fertility deity associated with farming and weather
bọ̀ - to return
àjò - trip


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Bàjò