Ọrẹ̀ṣotú
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọrẹ̀ṣotú
1. Ọrẹ̀ is a prominent leader; Ọrẹ̀ is a member of the Òṣùgbó. 2. Ọrẹ̀ has created an elder of the Òṣùgbó cult.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọrẹ̀-ṣe-otú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọrẹ̀ - Ọrẹ̀; a hunting and fertility deity associated with farming and weatherṣe - make
otú - elder of the Òṣùgbó secret society; prominent one
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU