Ọpẹ́yímiká
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọpẹ́yímiká
Thankfulness surrounds me. I'm surrounded by things that make me give thanks.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọpẹ́-yí-mi-ká
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọpẹ́ - thankfulness, gratefulness, thanksgivingyí...ká - surround
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL