Ọpẹ́túndé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọpẹ́túndé

Another reason to be thankful.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọpẹ́-tún-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọpẹ́ - grace, permission, gratitude
tún - again
- arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Túndé