Ọpẹ́sànyà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọpẹ́sànyà

Thankfulness repays (you) for suffering.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọpẹ́-sàn-ìyà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọpẹ́ - praise, thanks
sàn - to pay
ìyà - suffering, punishment


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL