Ọnádèmúrẹ̀n
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọnádèmúrẹ̀n
Artistry has created another (one).
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Ògúndèmúrẹ̀n
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọnà-di-èmúrẹ̀n
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọnà - artistrydi - become
èmúrẹ̀n - another (òmíràn, ìmíì)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU