Ọnànóìkí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọnànóìkí

Art has notability.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọnà-ní-òìkí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọnà - artistry
- have, own; in
òìkí - fame, notability (òkìkí)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Nóìkí