Ọmátárá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmátárá
A child is like family. See: Ọmọ́tárá.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmá-tó-ará
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọma - child (ọmọ)tó - suffice for, is as prominent as
ará - family, kin
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OKITIPUPA