Ọmọtíaníkẹ
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọtíaníkẹ
A child whose care we cherish/take seriously.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-tí-a-ní-ìkẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childtí - that
a - one who
ní - have, own; in
ìkẹ́ - care, love
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL