Ọmọmitórera
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọmitórera
My child is enough to show off.
Àwọn àlàyé mìíràn
A child to be proud of. A child to be pampered. A child one can show off.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-mi-tó-re-ara
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childmi - my
tó - enough, suffice
re - love, desire, admire
ara - body