Sísọ síta
The child has honour.
See: Oyèlọ́wọ̀, Adélọ́wọ̀
ọmọ-ní-ọ̀wọ̀
Ó pọ̀ ní: OYO
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.